Bi kii ba a ṣe pe Ọlọrun ṣi wa
lẹyin igbakeji Aare orileede yi, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo ni, boya oni ni ki ba ri
aye mọ latari ba a ṣe gbọ pe diẹ lo ku ko padanu ẹmi ẹ sinu ijamba ọkọ baalu
kekere, iyẹn Chopper to sṣẹlẹ niluu Kabba nipinlẹ Kogi lọsan onii.
AWIKONKO gbọ pe ipolongo ibo
saa keji Aarẹ Buhari atigbakeji rẹ ni wọn lo ba lọ sipinlẹ Kogi ko to di pe
baalu kekere ọhun yọwọ lasiko to fẹẹ ba silẹ.
Ṣugbọn, gẹgẹ bi agbenusọ fun Ọṣinbajo,
Ọgbẹni Laolu Akande ṣe sọ, ko si ẹnikẹni to farapa ninu ijamba naa.
No comments:
Post a Comment