Folukẹ Aduragbemi, Ọṣun
Wọnyi ni fọto tawọn agbaagba ajọ ṣọọṣi Katoliiti, iyẹn,
Catholic ba Gomina ipinle Ekiti ya lọjọ Fraide ana.
Lara awọn to wa ninu fọto yi ni akọwe fun Catholic
Caritas Foundation of Nigeria (CCFN), Rev. Fr. Dr. Uche Obodochina; Biṣọọbu agba ti ẹka ṣọọṣi Catholic nipinlẹ Ṣokoto, to tun jẹ oludasilẹ Kukah
Centre, Bishop Matthew Hassan Kukah; Gomina ipinlẹ
Ekiti, Dọkita
Kayọde Fayẹmi.
No comments:
Post a Comment