Bọsun Ọlaniyi, Abeokuta
Aarẹ orileede Naijiria, Ọgagun
Muhammadu Buhari ti bori idibo Aarẹ ti wọn ṣe nipinle Ogun pẹlu bo ṣe mu ijọba
ibilẹ mẹrinla ninu ijọba ibilẹ ogun to wa nipinlẹ naa.
Ohun ta a gbọ ni pe ijọba ibilẹ
mẹfa pere ni Alaaji Atiku Abubakar fi bori Aarẹ Buhari. Bi esi ibo naa ṣe lọ ni
yii.
IJEBU-ODE LG
APC – 12,850
PDP - 7,253
IJEBU NORTH EAST LG
APC - 6,435
PDP - 5,149
REMO NORTH LG
APC - 5,659
PDP - 6,269
ODEDA LG
APC - 10,049
PDP - 4,995
ABEOKUTA NORTH LG
APC - 22,044
PDP - 7,528
SAGAMU LG
APC – 20,875
PDP - 16,532
IMEKO-AFON LG
APC - 6,425
PDP - 6,689
OGUN WATERSIDE LG
APC - 6,889
PDP - 8,262
EGBADO SOUTH LG
APC - 12,934
PDP - 10,709
OBAFEMI OWODE LG
APC - 16,243
PDP - 7,938
IKENNE LG
APC - 10,283
PDP - 8,708
ABEOKUTA SOUTH LG
APC - 26,462
PDP - 13,853
ADO ODO/OTA LG
APC - 33,348
PDP - 20,352
EWEKORO LG
APC - 10,060
PDP - 5,101
IFO LG
APC - 23,895
PDP - 8,968
IJEBU NORTH LG
APC – 13,974
PDP -16,196
ODOGBOLU LG
APC – 10,130
PDP –
10,137
IPOKIA
APC – 14,686
PDP –
12,313
YEWA NORTH
APC – 10,434
PDP –
10,388
IJEBU EAST
APC – 7,287
PDP –
7,315
No comments:
Post a Comment