RONALDO TUN TAYỌ YATỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, January 17, 2019

RONALDO TUN TAYỌ YATỌ

Bi awon alase egbe agbaboolu Juventus se gba Christiano Ronaldo lodun o lo ti so eso rere fun won o.
Lojo Alaaruba, o se won lore kan to joju.

Oun lo gba ami ayo eyo kan soso ti won fi na AC Milan ninu idije Italian Super Cup, ti Juventus si gbe ife eye naa lo sile.

Pelu idunnu ni Ronaldo naa se soro nipa aseyori naa.

Se alangba to be sile lati ori igi iroko, o ni bi eni kan ko yin oun, oun a yin ara oun.

Lati: IROYIN OWURỌ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI