POGBA GBE ORIYIN FUN SOLSKJAER - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, January 17, 2019

POGBA GBE ORIYIN FUN SOLSKJAER

Ọkan lara awọn gbajumọ agbabọọlu fun Manchester United, Paul Pogba ti sọ pe asiko ti ẹgbẹ agbabọọlu naa yoo ṣe daadaa ju ni wọn wa yi, ti wọn yoo si fi oju gbogbo awọn alatako wọn gbole nibi ifigagbaga to ba pa wọn pọ.

O ni ẹgbẹ agbabọọlu Man U yoo tayọ labẹ akọnimọngba fidihẹ wọn, Ole Gunnar Solskjaer ju Jose Mourinho lọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI