Lati nnkan bi aago mẹjọ kọja iṣẹju mẹtadinlọgbọn ti igbakeji Aarẹ tẹlẹri lorileede yi, Alaaji Atiku Abubakar ti kede sita lori ẹka ayelujara ti Twitter pe oun ti balẹ si ilu-ilu ilẹ Amẹrika tii ṣe Washington DC lawọn olofẹ ẹ ti bẹrẹ sii fi awọn ọta okunrin naa ṣẹlẹya pe oju ti wọn, ọga awọn pada de ibi tawọn eeyan ko lero pe o le lọ.
Gẹgẹ bi iroyin yi to tẹ AWIKONKO lọwọ ṣe sọ, Atiku ati Sẹnetọ Bukọla Saraki to je Aarẹ ile igbimọ aṣofin agba lorileede yi lo tẹle e lọ gbatẹgun nibẹ.
A gbọ pe ipade alaafia ni Atiku lọ ọ ṣe pẹlu awọn alaṣẹ orileede US, ta a si gbọ pe ko ṣẹyin Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ
Just arrived Washington D.C for meeting with US government officials, Nigerians living in D.C metropolis and the business community. -AA
fffff
No comments:
Post a Comment