O maa n
dara ki ọkunrin maa mọ riri iyawo ẹ, bẹẹ naa lo dara ki obinrin maa fi ifẹ han
si ọkọ, paapaa niru asiko bi ojọ ibi.
Wọn yii
gan an lọrọ to lọ nibamu pẹlu bi gbajumọ oṣere tiata oloyinbo nni, Richard Mofẹ
Damijo ṣe fi imọriri han si iyawo, Arabinrin Jumọbi Abikẹ Damijo fun ti ayẹyẹ ọjọ ibi ati ayẹyẹ ọdun
mejilelogun ti wọn ti jọ n gbe gẹgẹ bi ọkọ ati aya.
No comments:
Post a Comment