Ẹsẹ ko gbero
ni gbogbo agbegbe Mapo niluu Ibadan lonii ọjọ kẹrinlelogun oṣu kinni, ọdun 2019
nigba ti Aarẹ orileede yi, Ọgagun Muhammadu Buhari; igbakeji ẹ, Ọjọgbọn Yẹmi
Ọṣinbajo; Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu APC, Aṣiwaju Bọla Ahmẹd Tinubu; Alaga lapapọ,
Kọmureedi Adams Ọshiọmolẹ; Gomina ipinlẹ Eko, Ọgbẹni Akinwunmi Ambọde atawọn
agbaagba to fi mọ awọn adije ninu ẹgbẹ oṣelu naa balẹ siluufun ipolongo idibo,
eyi ti yoo waye loṣu to m bọ.
Ọla Eyitayọ, Ọyọ
No comments:
Post a Comment