AGBẸJỌRO TU AṢIRI TRUMP, O LAWỌN YI IBO LORI ẸRỌ AYELUJARA NI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, January 17, 2019

AGBẸJỌRO TU AṢIRI TRUMP, O LAWỌN YI IBO LORI ẸRỌ AYELUJARA NI

Agbẹjọro tẹlẹ fun Aarẹ orileede Amẹrika, Donald Trump, iyẹn Ọgbẹni Michael Cohen ti tu aṣiri nla nipa ibo to gbe Aarẹ Trump wọle gẹgẹ orileede naa. Cohen lawọn yi ibo fun Trump lori ẹrọ ayelujara lọdun 2015 ni.
O loun lọ ọ ba olori ileeṣẹ kan to mọ nipa ayelujara daadaa, iyẹn Ọgbẹni John Gauger pe ko bawọn kọ nnkan ti yoo fun Trump nibo rẹpẹtẹ lori ayelujara to jẹ ti tawọn sọrọsọrọ, CNBC.

Ile ẹjọ ti wa ju Cohen, ẹni ọdun mejilelaadọta naa sẹwọn ọdun mẹta gbako pe o lọwọ ninu idibo magomago to gbe Trump wọle.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI