ADESINA DI AKOWE IROYIN FUN GOMINA IPINLE OSUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, December 4, 2018

ADESINA DI AKOWE IROYIN FUN GOMINA IPINLE OSUN


Gomina ipinle Osun, Gboyega Oyetola ti kede Ogbeni Adeniyi Francis Adesina gege bi akowe agba feto iroyin fun sa a isejoba e.

Gege bi iroyin to te AWÍKONKO lowo se so, ana ni Gomina Gboyega Oyetola kede Ogbeni Francis Adesina gege bii akowe iroyin e niwaju awọn osise e niluu Osogbo.

AWIKONKO gbo pe igbakeji olootu agba fun iwe iroyin The Nation ni Ogbeni Adesina ti won lomo bibi ilu Ilesa ni ti sise ki Gomina Oyetola to o yan an.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI