WON WA OMODUN MERINLA TO SONU N'ILORIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, November 12, 2018

WON WA OMODUN MERINLA TO SONU N'ILORIN

Titi dasiko ta a sakojopo iroyin tan la ko tii gbo pe won ti ri omodekunrin eni odun merinla kan ti won loo dawati lati ojo Abameta to koja yi.


Audu Olayinka Ibrahim loruko omodekunrin naa, ti won ni nnkan bi aago mẹfa irọlẹ ọjọ Sátidé to koja yi ni won ti n wa, ti won ko si tii ri titi dasiko ta a pari iroyin yi.

Adugbo Osere nitosi Asadam, Ilorin nipinle Kwara ni won láwọn kan ti ríi gbeyin, ti kò sí seni to mo ibi to wa titi di ba ti n soro yi.

Ohun tá a gbo ni pe ko tii síbí tawon obi Ibrahim ko tii wa omo won yi dé, won ti lòó f'oro naa to awon olopaa leti.

Fún ẹnikẹni tó bá rí Audu Olayinka Ibrahim, ko tete pe awon nomba yii; 08035788571 07033781858 07069128002

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI