WON LAWON OOGUN ORUN LU PASITO PA NITORI ISOJI ISE-IYANU OWO TO FEE SE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, November 8, 2018

WON LAWON OOGUN ORUN LU PASITO PA NITORI ISOJI ISE-IYANU OWO TO FEE SE



Bo tile je pe AWIKONKO ko tii le fidi asiri iku to pa gbajumo Pasito kan ti won pe oruko e ni Rev Augustina Drumgbe mule, sugbon oro tawon eeyan n so nipa pasito naa mu ifura dani.

AWIKONKO gbo pe onii tii se Tosde lo ye ki eto akanse adura olojo meji ti won ti fe e sise iyanu owo, iyen Miracle Money waye, sugbon oru moju Monde ni obinrin naa dagbere faye.

Bawon kan se n so pe eto akanse adura ise iyanu owo naa kii soju lasan, nitori pe Olorun ko see se ki Olorun ro ojo owo kale lati orun.


Bee lawon kan n so pe Pasito naa ati oko e, Apositeli Joshua Drumgbe gbona pupo to ba di oro ise iyanu.

A gbo pe opo awon eeyan ni won ti n mura sile fun ipade adura, ta a ko sì tii le fidi e mule pe yoo waye mo.

Pasito Joshua la gbo pe o kede iku iyawo fawon eeyan.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI