Bi e se n ka iroyin yi, to ku ojo mokanla tijoba Gomina Aregbesola yoo kogba wole
l'Osun, gomina ti fowo si yiyan olori awon osise ijoba nipinle Osun,
Dokita Oyegbade Olowogboyega gege bii adele akowe funjoba.
Olowogboyega
ni won mu lati ropo Senato Mudashiru Hussein eni to ti di komisanna fun
ajo eleto ikaniyan lorileede yii, NPC bayii.
Saturday, November 17, 2018
OYEGBADE OLOWOGBOYEGA DI ADELE AKOWE FUNJOBA IPINLE OSUN
Tags
# Oselu
PIN-IN KAAKIRI
NIPA IROYIN AWIKONKO
Oselu
Tags:
Oselu
PÍN-IN KÁÀKIRI
Author Details
Ile-iṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL lo n gbe IROYIN AWIKONKO jade pẹlu ontẹ Ijọba orilẹ-ede Naijiria labẹ ajọ iforukọsilẹ nni, iyẹn CORPORATE AFFAIRS COMMISSION. A fẹ ki ẹyin ti ẹ n ka Iroyin Awikonko mọ daju pe a ko ni i gba ẹnikẹni laaye lati ṣe ẹda iroyin wa, tabi gbe e jade ninu iwe iroyin min in lai gba aṣẹ lọwọ awọn alaṣẹ wa, ẹsẹ ofin la o fi gbe onitọhun. Bẹẹ, a ko ni fẹ ki ẹnikẹni ṣi iroyin wa ka, nitori pe iwadii kikun la n ṣe ka to le gbe iroyin jade, nitori naa, bi ẹ ba ka ifọrọwerọ pẹlu eeyan, ohun ti ẹni naa ba sọ, ki i ṣe awa la sọ ọ, ẹni naa lo sọ bẹẹ. Fun alaye lẹkunrẹrẹ, tabi ipolowo ọja yin, ẹ le kan si wa lori: +2347012342712.