OLORI BADIRAT, IYAWO ALAAFIN OYO SAYEYE OJO IBI ODUN MOKANDINLOGBON - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, November 3, 2018

OLORI BADIRAT, IYAWO ALAAFIN OYO SAYEYE OJO IBI ODUN MOKANDINLOGBON

Olori Badirat Olaitan Ajoke Adeyemi, iyawo ti Alaafin Oyo fẹ gbeyin, to bimo ibeji laipe yi re é, o ni layeye ọjọ ibi é.

Lara awon to sì gbé sórí ìkànnì eka ayelujara re é.




PÍN-IN KÁÀKIRI