Ka ni awon olopaa ipinle Taraba tete gbera lo sagbegtbe kan ti won ni gendekunrin kan ta a ko tii moruko dasiko yi ti gun ore e pa ni, o see se komokunrin naa ti wa logba ewon bayii, ko si maa gbategun lowo.
|
Eni ti won sa pa |
Aipe yi la gbo pe awon mejeeji jo n ta ohun sira won, sugbon ta a gbo pe ore yi loo mu ada, o si fi sa ore e pa.
|
Eni to sa ore e pa |
Ohun ta a gbo ni pe odomokunrin naa ti na papa bora, ti ko si tii seni to mo ibi to wa dasiko ta a ko iroyin yi tan.