NITORI iPHONE, WON PA SEIYEFA DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, November 17, 2018

NITORI iPHONE, WON PA SEIYEFA DANU

Bo tile je pe owo olopaa ipinle Bayelsa ti te awon odaran meji ti won pa akekoo ileeko giga ti Niger Delta, iyen Niger Delta University, Seiyefa danu lojo Tosde to koja yi latari owo ti won jo n beere lowo ara won.


Ohun ta a gbo pe awon eso aabo ti ipinle Bayelsa la gbo pe won rowo to awon omodekunrin meji yi, Junior Danumunabo, eni ogun odun ati Ezeago. Agbegbe Amarata la gbo pe owo ti te won ni nnkan bi aago marun un aaro, lasiko ti won n sun lowo.


Lesekese towo ti te won la gbo pe won ti loo fa won le olopaa ipinle naa lowo.














PÍN-IN KÁÀKIRI