Se lawon eeyan kawo mori, paalaa awon oloja nigba ti Gomina ipinle Ekiti, Dokita Kayode Fayemi kede pe oun ti oja Oba to gbajumo daadaa laarin ilu naa pa.
Gomina ana nipinle naa, Ogbeni Ayodele Fayose lo ko oja yi lasiko ijoba e.
Ko si nnkan meji to mu ki Gomina Fayemi pase naa, bi ko se ayewo to se lo sibe, to si ni bi won se ko awon apakan ninu oja naa ko bojumu, ati pe ise ko tii pari, to si see se ko sakoba fawon eeyan.
No comments:
Post a Comment