Ni bayii, ijoba apapo ti kede isinmi olojo kan fun ayeye naa, eyi to maa waye lojo Isegun to n bo yii. Ninu oro Minisita fun oro abele, Ajagunfeyinti Abdulrahman Dambazau to se ikede ohun loruko ijoba apapo orile-ede yii lo ti ni ki awon Musulumi lo akoko naa lati fi wa ojuure Olorun, ki won si gbiyanju fi iwa daadaa jo Anobi.
O fi kun un pe, iwa ododo, iwa mimo, ifaaye-gba omlakeji ati ibagbepo alaafia ti Ojise nla ni lo fi gbayi julo lagbaye.
MAGASINNI ALORE