KAYEEFI NLA; WON JI AWON IBEJI GBE NI DAURAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, November 17, 2018

KAYEEFI NLA; WON JI AWON IBEJI GBE NI DAURAN

Iroyin to te AWIKONKO lowo lai pe yi ti je ko di mi mo pe won ti ji awon omodekunrin meji yi, ti won tun je ibeji gbe nipinle Zamfara.

Hassana ati Hussaina loruko awon ibeji naa, abule Dauran to wa nijoba ibile Zumi nipinle naa ni won ti ji won gbe gege ba a se gbo.

Ogbeni Abudl Balarabe to gbe oro naa sita lati fi to awon omo Naijiria leti, paapaa bi won ba kofiri won.

PÍN-IN KÁÀKIRI