IPADE ALAAFIA AGBAYE: BUHARI TI DE FRANCE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, November 10, 2018

IPADE ALAAFIA AGBAYE: BUHARI TI DE FRANCE

Bi e se n ka iroyin yi lowo, Aare orileede Naijiria, Muhammadu Buhari ti bale si orileede France nibi ti yoo ti loo kopa nibi ipade alaafia agbaye, to je akoko iru e, iyen Paris Peace Forum, ti yoo waye lojo Sande ola titi di Tusde, iyen ojo kokanla si ojo ketala osu yii.


Awon gomina meta la gbo pe won tele Buhari lo, awon naa ni Gomina ipinle Anambra, Aminu Masari; Gomina ipinle Katsina, Willie Obiano ati Gomina ipinle Ekiti, Kayode Fayemi














PÍN-IN KÁÀKIRI