EYI NI BAWON OSISE IJOBA SE PA ALABOYUN DANU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, November 14, 2018

EYI NI BAWON OSISE IJOBA SE PA ALABOYUN DANU

Iroyin naa kii se iroyin to dun mo enikeni ninu rara pelu bi keke Maruwa kan se nijamba to po repete, to si pa awon eeyan to wa ninu e, to fi mo alaboyun kan.

 

Gege bi iroyin to te AWIKONKO lowo se so, won lawon osise ijoba ti won gba owo ori moto, iyen Revenue ni won n le moto akeru nla kan lagbegbe Ikot Ekpene, nijoba ibile Aba South.

 

Moto akeru naa la gbo pe nibi to ti n salo lo ti loo kolu Keke Maruwa yi, eyi ti won ni awon meta lo wa ninu e, to si je pe awon meji lo sagbako iku, to fi mo alaboyun.

Moto akeru naa la gbo pe ko duro to fi salo, ta a si gbo pe awon osise ijoba yi naa ko duro.

PÍN-IN KÁÀKIRI