AWON OMO NAIJIRIA TI WON FE E LE DANU RE O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, November 7, 2018

AWON OMO NAIJIRIA TI WON FE E LE DANU RE O

Bi e se n ka iroyin yi, ko ni pe ti orileede Cambodia yoo fi le awon gendekunrin meji yi danu latari ija ti won ni won n bara won ja, ti won si n da alaafia ilu laamu.


Nmegbu Joseph, eni odun mejidinlogbon ati Micahel Daniel, eni odun metalelogoji la gbo pe ile ounje igbalode kan lawon mejeeji ti gbena woju ara won, ti won si ba opolopo dukia je nibe, iyen lojo Monde ijeta to koja yi.


adugbo kan ti won ni 392, Sangkat Beung Keng Kong1, Khan Chamkamorn, Phnom Penh lawon mejeeji ti lu ara won, ko too di pe awon eso alaabo wa ko won.












PÍN-IN KÁÀKIRI