Foto omo kekere omodun meji kan, Abul Fadl Abbas Mustapha, ti won lomo
Mustapha Ingawa, to je Kopa ti wo yinbon pa nibi ikolu egbe awon elesin musulumi, Shi’ites atawon eleto aabo niluu Abuja lai pe yi.
Mustapha ta a gbo pe akeko jade leka Business Administration lo n si orileede baba e lowo niluu Abuja, asita ibon lo si ba, ko too ku.
Lojo ti won sinku e ni omo e ti lo n wo aworan e, tawon eeyan to wa nibi isnku naa si sare ya foto omo yi.
Saturday, November 10, 2018
AWON EEYAN SI N SORO LORI OMO TI WON PA BABA E DANU
Tags
# KAYEEFI
PIN-IN KAAKIRI
NIPA IROYIN AWIKONKO
KAYEEFI
Tags:
KAYEEFI
PÍN-IN KÁÀKIRI
Author Details
Ile-iṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL lo n gbe IROYIN AWIKONKO jade pẹlu ontẹ Ijọba orilẹ-ede Naijiria labẹ ajọ iforukọsilẹ nni, iyẹn CORPORATE AFFAIRS COMMISSION. A fẹ ki ẹyin ti ẹ n ka Iroyin Awikonko mọ daju pe a ko ni i gba ẹnikẹni laaye lati ṣe ẹda iroyin wa, tabi gbe e jade ninu iwe iroyin min in lai gba aṣẹ lọwọ awọn alaṣẹ wa, ẹsẹ ofin la o fi gbe onitọhun. Bẹẹ, a ko ni fẹ ki ẹnikẹni ṣi iroyin wa ka, nitori pe iwadii kikun la n ṣe ka to le gbe iroyin jade, nitori naa, bi ẹ ba ka ifọrọwerọ pẹlu eeyan, ohun ti ẹni naa ba sọ, ki i ṣe awa la sọ ọ, ẹni naa lo sọ bẹẹ. Fun alaye lẹkunrẹrẹ, tabi ipolowo ọja yin, ẹ le kan si wa lori: +2347012342712.