Titi dasiko yi lawon eeyan si fi n soro ayeye ojo ibi odun merinlelogbon (34) ti gbajumo olorin taka-sufe nni, Innocent Ujah Idibia, eni tawon eeyan tun mo si 2Face se fun iyawo e, Annie Idibia lojo Tusde to koja yi, iyen ojo ketala osu yi.
Eyi lawon Foto bi ayeye ojo ibi naa se lo si....