WON N WA ZAINAB TO FE SEGBEYAWO LOSE TO N BO O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, October 18, 2018

WON N WA ZAINAB TO FE SEGBEYAWO LOSE TO N BO O

Titi di bi e ti n ka iroyin yi ni won si n wa odomobinrin arewa kan ti won pe oruko e ni Zainab Hassan, eni ta a gbo pe ose to m bo, iyen ojo kerindinlogbon osu yi lo fe e segbeyawo e pelu ololufe e.



PÍN-IN KÁÀKIRI