Ileese Asset
Management Corporation of Nigeria (AMCON) ti so pe igbese lati ta banki Polaris
lodun meji sasiko yi ti n lo lowo, ko si ni pee pari.
Ahmed Kuru,
to je alaga ileese naa lo fidi oro yi mule nibi iforowero kan to se niluu Eko
lai pe yii.
Be o ba
gbagbe, osu to koja yi ni Polaris gbajoba banki Skye latari bi won se ri owo to
ye ki won san san.
Kuru so pe
awon ti baa won alakoso banki Polaris soro, won si ti fenuko pe kawon ta banki
naa laarin odun meji sasiko yi.