ORUKO ALLAH JADE NINU ODO NILUU ILORIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, October 28, 2018

ORUKO ALLAH JADE NINU ODO NILUU ILORIN

Ara mi o riri, mo ri ori ologbo lori ate, kayeefi nisele naa si n je fawon ara agbegbe Amule niluu Ilorin, ipinle Kwara lose ta a sese lo tan yi nigba ti won deede ri nnkan funfun lori odo to gba agbegbe naa koja.


Aaro kutu la gbo pe awon ti won ji lo sodo ri ohun iyanu yii, ni won ba mu iroyin ohun ti won ri yii to awon to wa nile lo.


Ariwo 'Alahu Akbar' lo gba enu gbogbo awon ti won ri ise iyanu nla yii.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI