NITORI DAPO ABIODUN, WON N FI IKU WA OLOYE EGBE OSELU APC KAAKIRI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, October 19, 2018

NITORI DAPO ABIODUN, WON N FI IKU WA OLOYE EGBE OSELU APC KAAKIRI

Bi iroyin to te AWIKONKO lowo lai pe yi ba fi le je otito, a je pe a fi ki okan lara awon oloye egbe oselu APC nipinle Ogun, Oloye Bode Mustapha tete maa wa ona bi yoo ti salo kuro nipinle naa, tabi ko kuro patapata lorileede Naijiria.


Ohun ta a gbo ni pe, awon kan ta a ko tii moruko won ni won n fi iku dunkoko mo Bode Mustapha, eni to tun je Bobagunwa ilu Egba.

AWIKONKO gbo pe ko si nnkan meji to mu ki won maa dunkoko mo Bode Mustapha to ti figba kan ri je omo ile igbimo asofin nipinle Ogun, bi ko se ti ipinu e lati sagbateru adije sipo gomina ipinle naa, Omoba Dapo Abiodun.

Ninu iwe esun ti Mustapha fi ranse sileese olopaa ipinle naa lati daabo bo emi e losan onii, eyi ti eda iwe naa te AWIKONKO lowo lo ti je ko di mi mo pe idunkoko naa ko seyin ti oselu to n lo lowo nipinle naa bayii.

Wonyii ni leta naa.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI