KO SI OWO, KO SI ISE NI BAYII O - AWON OSISE FARIGA O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, October 30, 2018

KO SI OWO, KO SI ISE NI BAYII O - AWON OSISE FARIGA O


Ajo awon osise kaakiri orileede Naijiria fi fariga pe bi ko ba si owo, awon ko nii pada senu ise won, ayafi bijoba orileede yi ba le dawon lohun nnkan ti won n fe.


Kaakiri orileede Naijiria ni iwode ifehonuhan ti n lo latari owo osu to kere ju tuntun ti won n beere fun.






Ekunrere iroyin naa n bo lai pe

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI