KAYEEFI NLA: PASITO DANA SUN ARA E - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, October 28, 2018

KAYEEFI NLA: PASITO DANA SUN ARA E

Bo tile je pe titi di bi a to sakojopo iroyin yi tan ni a ko tii le fidi e mule nipa bi Pasito kan se deede gba emi ara e lojiji, to si se be e soda sorun alakeji.


Ohun ta a gbo ni pe opin ose to sese koja yi lawon ara adugbo ti Pasito naa n gbe nipinle Enugu sa deede rii pe ile n jo.


Lara awon to fisele naa to wa leti, sugbon ti won ko daruko Pasito naa fun wa je ko ye wa pe se lo mon on mo gba emi ara re lati awon isoro to n la koja.

Kayeefi nla si nisele naa si n je fawon ara adugbo naa, ko da a, awon to gbo nipa e lo si n ba idile okunrin naa kedun.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI