Odomodekunrin nni, Ogbeni Michael Adebowale Thomas ti gbe fiimu agbelewo tuntun jade, oruko fiimu naa ni 'OKOTO'.
Fiimu naa ta a gbo pe egbelegbe milionu naira ni won sii lawon gbajumo osere tiata ti kopa ninu e.
Lara
awon to kopa ninu fiimu naa ni Mide Martins Owoh, Sunkanmi Omobolanle,
Regina Chukwu, Adeyemi Adeyemo, Jaiyaolaoluwa Azeez, Akin Kolapo,
Bukunmi Oluwasina, Wasiu Adedeji, Ibrahim Babalola, Ibrahim Dauda, Ladi
Folarin ati Thomas Adebowale funra e.
Opo
awon ti won ti n gbo nipa fiimu naa ni won ti n kan saara si olootu e,
iyen Michael Thomas Adebowale funra e pelu ise to se nipa itan naa.
Kayode Adebayo la gbo pe o dari fiimu naa.