Eyi ni lati je ki gbogbo eeyan mo pe iro to jinna si otito ni iroyin naa, digbi si ni ara Oloye Dokita Earnest Sonekan wa bi e ti n ka iroyin yi lowo.
Akowe ijoba ipinle Ogun, Taiwo Adeoluwa fidi e mule pe awon to gbe iroyin naa jade ko se iwadii to ye, ki won to bere sii fon on kaaakiri ero ayelujara.
A toro aforijin wi pe iru iroyin bayii ko tun jade lori AWIKONKO mo.