AMOSUN FE E KO GBONGAN AYEYE NLA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, October 25, 2018

AMOSUN FE E KO GBONGAN AYEYE NLA

Gomina Ibikunle Amosun tipinle Ogun to kede sita pe igbese ti n lo lowo lati ko gbongan ayeye nla ti yoo gba to egberun marun un awon eeyan.


Gbongan ayeye Asa, June 12 to wa niluu Abeokuta ni Gomina Amosun ti soro yi lasiko to n bawon eeyan soro nibi ipade ita gbangba ti eto isunna owo todun 2019 to n lo lowo.


Ko si nnkan meji to mu ki Gomina Amosun kede oro yi sita bi ko se ti bi gbongan ti June 12 naa ko se gba awon eeyan, to je pe pupo ninu awon to wa nibe ni won ko ribi jokoo sii.

Gomina Amosun so pe titi toun yoo fi gbe ijoba kale lodun 2019 loun yoo fi maa sise, ti ise ko si nii duro.
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI