OMO TUNTUN PELU ORUKO ALLAH NINU ETI E RE O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, September 20, 2018

OMO TUNTUN PELU ORUKO ALLAH NINU ETI E RE O

Ohun iyanu kan sele lagbegbe Olorunsogo, ni Mushin, lojo meloo kan seyin, toko-taya kan ti won je musulumi ni won ba oruko Olorun, iyen Allahu leti omo tuntun ti won bi.


Bi won se sakiyesi ohun iyanu yii ni won pe awon eeyan pe ki won wa a wo ohun ara tawon ri, ko pe rara ti okiki kinni ohun fi kan de gbogbo adugbo yii, tawon n jade ni mesan-an-mewaa lati wa a wo omo iyanu yii.


Ko sohun meji tawon eeyan n wi ju pe iyanu Olorun kan tun ree 

LATI: OJUTOLE-TOKO


PÍN-IN KÁÀKIRI