O MA SE O: E WO BI BAALE ILE SE LU IYAWO E - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, September 12, 2018

O MA SE O: E WO BI BAALE ILE SE LU IYAWO E

Eyi ni foto to n lo kaakiri ori ero ayelujara bayii, nibi ti won ni Baale ile kan ti lu iyawo e, ti ara e si bo yama-yama.


Bo tile je pe AWIKONKO ko tii le fidi obi tisele naa ti sele mule, sugbon bi foto naa se n lo kaakiri lo je ka muu wa fun un yin lati ri.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI