MI O LE GBAGBE IYA TO JE MI NIGBA TI MO BI OMO AKOKO - MERCY AIGBE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, September 17, 2018

MI O LE GBAGBE IYA TO JE MI NIGBA TI MO BI OMO AKOKO - MERCY AIGBE

IGBAGBOYEMI ESUPOFO

Gbajugbaja osere tiata Yoruba nni, Mercy Aigbe, ti salaye ohun toju e ri lasiko tobi akobi e, Michelle. Osere omobibi ilu Edo yii so pe iya to je oun lasiko naa ju eyi to je maalu to kangun si fulaani lo.


E gbo bo se wi 'Mi o le gbagbe iru iya nla to je mi nigba ti mo bi Michelle, gbogbo nnkan ini mi pata ni mo ta ni Yabaa ka le e rowo jeun, atowo ileewe e. Oju mi ri to, mo je moyo iya.'

Fawon ti ko ba mo, ileewe yunifasiti 'UNILAG' ni Mercy wa to fi bi akobi e yii, sugbon awon obi okunrin to bimo fun yii ko gba ki won fera. Ohun to fa a niyen to fi je pe osere yii nikan lon da gbo bukaata omo e yii.

Leyin opolopo odun lo pade okunrin oloteeli ti won n pe ni Larry Gentry, omo kan lo bi fun oun naa kaarin won too daru.

LATI: OJUTOLE-TOKO

PÍN-IN KÁÀKIRI