MANIJA LIVERPOOL KOWE FISE SILE LOJIJI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Saturday, September 15, 2018

MANIJA LIVERPOOL KOWE FISE SILE LOJIJI

SERUBAWON AYEGBAJEJE

Kani egbe agbaboolu Liverpool, tawon obinrin mo pe manija won, Neil Redfearn yoo kowe fipo sile ni, bo ya won ki ba ti tete bere sii be e lati ma se gbe igbese naa, nitori ta a gbo pe lojiji lo ba won.


Ko si nnkan meji to mu ki manija naa kowe fipo e sile lojo Tosde to koja yi, bi ko se ti idije ti won padanu sowo egbe agbaboolu Manchester United lopin ose to koja yii, aami ayo marun un si oodo (5-0) ni won fi padanu.

Latigba naa la gbo pe inu Neil ko ti dun, to si je pe asiko ti won n mura sile fun adije ti won fe e gba lati fi koju egbe agbaboolu Durham ninu adije Continental Tyres Cup lojo Sande ola lo dee de fise sile.

https://mpulse.mtnonline.com/#utm_source=awikonko&utm_medium=banner&utm_campaign=mpulse
Ale ojo Tosde la gbo pe Neil fi ipinu e yi han sawon alakoso egbe agbaboolu naa, to si je pe nigba ti won de papa isere ti won ti fe e mura sile fun idije naa ni won ti je kawon agbaboolu mo nipa e, to si je iyalenu fun won.

PÍN-IN KÁÀKIRI