Bee lo tun so pe ola, iyen Ojobo, Tosde loun yoo foju eni toun fe e fa kale gege bi adije sipo gomina ninu egbe oselu APC han fun gbogbo awon to ti n fee mo ibi toun n lo.
O ni ipo gomina toun fe e gbe kale lodun 2019 naa, ko se e gbe kale fun eni toun ko le finu tan.
Ekunrere iroyin naa n bo lai pe. E ku ojulona.
No comments:
Post a Comment