SERUBAWON AYEGBAJEJE
Titi
dasiko yii lawon akekoo ileewe giga Ambrose Alli University, to wa
niluu Ekpoma, nipinle Edo si n baraje pelu bawon omo egbe okunkun se
yinbon pa awon omoleewe mewaa.
AWIKONKO gbo pe ija
lo sele laarin okan ninu awon omo egbe okunkun yii pelu elomi-in, ti
won si bawon pari e, sugbon omo egbe okunkun yii so pe oun ko ni i gba
afi ti eni to ba oun ja yii ba ra aso mi-in foun.
Lasiko ayeye ikekoo-jade tawon akekoo yii se laduugbo kan ti won n pe ni Judges's Quarter ni Ekpoma ni wahala yii ti sele.
Thursday, September 20, 2018
EYI NI BI WON SE PAWON AKEKOO AMBROSE ALLI DANU
Tags
# KAYEEFI
PIN-IN KAAKIRI
NIPA IROYIN AWIKONKO
KAYEEFI
Tags:
KAYEEFI
PÍN-IN KÁÀKIRI
Author Details
Ile-iṣẹ AWIKONKO MEDIA CHANNEL lo n gbe IROYIN AWIKONKO jade pẹlu ontẹ Ijọba orilẹ-ede Naijiria labẹ ajọ iforukọsilẹ nni, iyẹn CORPORATE AFFAIRS COMMISSION. A fẹ ki ẹyin ti ẹ n ka Iroyin Awikonko mọ daju pe a ko ni i gba ẹnikẹni laaye lati ṣe ẹda iroyin wa, tabi gbe e jade ninu iwe iroyin min in lai gba aṣẹ lọwọ awọn alaṣẹ wa, ẹsẹ ofin la o fi gbe onitọhun. Bẹẹ, a ko ni fẹ ki ẹnikẹni ṣi iroyin wa ka, nitori pe iwadii kikun la n ṣe ka to le gbe iroyin jade, nitori naa, bi ẹ ba ka ifọrọwerọ pẹlu eeyan, ohun ti ẹni naa ba sọ, ki i ṣe awa la sọ ọ, ẹni naa lo sọ bẹẹ. Fun alaye lẹkunrẹrẹ, tabi ipolowo ọja yin, ẹ le kan si wa lori: +2347012342712.