Bi e se n ka iroyin yi lawon eeyan si n gbe okunrin kan ti won pe oruko e ni Daniel Udoh se epe ribiribi lori bo se n ko ibasun fun omo e omodun meje lojoojumo.
Gege bi AWIKONKO se gbo, Daniel Udoh ti won ni oun ni oludasile soosi Jesus Is A Barrister to wa lagbegbe Akapabuyo nipinle Cross River la gbo pe o pelu awon odaran mokandinlogorin (79) awon odaran ti ileese olopaa nipinle naa foju won han faqon oniroyin lai pe yi niluu Calabar.
Nigba ti won lo n jewo ese e, Daniel Udoh so pe looto ni ati pe ise esu, nitori naa, o bebe pe ki won dariji oun.
AWIKONKO gbo pe omo naa, omodun meje naa, ta a foruko bo lasiri ti wa ni osibitu to ti n gba itoju nitori ta a gbo pe Daniel fa idi omo e naa ya perepere koja afesnuso.
No comments:
Post a Comment