AYEFELE OKEOWO
A fi ki Olorun ko awon okunrin oloju-komu-o-lo yo lowo awon obinrin, paapaa bo se je pe omu awon obinrin lo maa n mu ki ara awon okunrin min in dide lai ti ri ihoho won.
A fi ki Olorun ko awon okunrin oloju-komu-o-lo yo lowo awon obinrin, paapaa bo se je pe omu awon obinrin lo maa n mu ki ara awon okunrin min in dide lai ti ri ihoho won.
Eyi lo nibamu pelu bi gendebinrin
kan to pe oruko ara re ni Jesus Babe lori eka ayelujara ti won n pe ni
'Istagram' ti so pe nitori omu oun to tobi daadaa lawon okunrin se feran
oun lori ero ayelujara.
Alaye to
se e ni pe pelu bi oun ki i se ko awon oro to dara lori eka ayelujara
yii, sibe awon eeyan to le ni egberun-un lona ogun ni won feran oun, o
si da oun loju doba pe nitori oyan oun to tobi daadaa lo je ki won maa n
te le oun lori 'instagram' yii.
.