SERUBAWON AYEGBAJEJE
Nnkan ko rogbo niluu Igede-Ekiti, nipinle Ekiti, pelu bawon adigunjale kan se yabo won nile ifowopamo kan to je ti Union, iyen Union Bank to wa niluu naa.
Lojuese ni won ti pa awon eso aabo to wa nibe, awon osise ile ifowopamo yii atawon onibaara won naa faragba ninu e.
Leyin tawon adigunjale yii pa awon eeyan tan, ni won gbe roburobu owo lo
AWIKONKO gbo pe awon olopaa ti bere ise lati wa awon adigunjale yii kan