WAHALA DE: SALVADOR, ALAGA EGBE OSELU PDP NIPINLE EKO TI DARAPO MO APC - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, August 27, 2018

WAHALA DE: SALVADOR, ALAGA EGBE OSELU PDP NIPINLE EKO TI DARAPO MO APC

Bi iroyin to te AWIKONKO lowo lai pe yi ba fi le je otito, a je pe a fi ki egbe oselu PDP mura daadaa, ki egbe naa ma ba a tun padanu ibo odun 2019 nipinle Eko si owo egbe oselu APC.


Gege bi iroyin to te AWIKONKO lowo naa se so, won ni alaga egbe oselu PDP nipinle Eko, Onarebu Moshood Salvador ti fi egbe naa sile bayii, o si ti loo darapo pelu egbe oselu APC.

Ekunrere iroyin naa n bo lai pe. E ku oju lona.

PÍN-IN KÁÀKIRI