Ariwo ikunle abiyamo lo gba enu awon
ara agbegbe Owode, Ota kan laaro ojo Abameta Satide to koja lohun nibi ijamba
tirela, boosi akero atawon moto min in, to se awon eeyam lese, tenikan si
gbagbe soda sorun alakeji.
Ohun ta a gbo ni pe ni nnkan bi aago
mefa ku oseju ni tirela IVECO ti nomba idanimo e je XB190MLF ni ijani e ja sonu
lori ere, gbogbo bi eni ti won loo wa tirela naa se n gbiyanju lati ma da
wahala sile, to ja so pabo, to si loo kolu boosi akero atawon moto marun min
in.
Lesekese ni agbero, iyen conductor
boosi naa ti won loun n pe ero sinu moto lowo ti ku, tawon eeyan repete si
farapa yannaayanna.
Agbenuso fawon eso oju opopona,
TRACE, Ogbeni Babatunde Akinbiyi fidi e mule pe awon lawon gbe oku okunrin naa
lo si mosuari jenera ti Ota, tawon to ku si wa nibi ti won ti gba itoju. O tun
je ko ye wa pe awon ti gbe awon moto naa lo si ogba ileese FRSC Ota tawon si ti
fa awako tirela naa lo si tesan olopaa Ota.
Ninu iroyin min in la tun ti gbo pe
tirela nla kan naa ti te obinrin kan ti won loun ati oko e jo n lati isooru pa
laaro ojo Satide Bakan naa.
AWIKONKO gbo pe ijanu tanka
elepo kan naa ta ko tii mo nomba idanimo e dasiko ta a sakojopo iroyin yi tan
lo ja sonu lojiji, to si loo kolu obinrin naa lrgbe titi.
Lesekese la gbo pe obinrin naa ti ta
teru nipa. Awon TRACE naa la gbo pe won gboku lo si mosuari jenera to wa ni Ota