Bi iroyin to n lo kaakiri orileede Naijiria bayii ba fi le je otito, a je pe a fi Buhari loo ba awon alale orileede yii lati maa rawo ebe siwon lori bawon Seneto meedogun ti won je omo egbe oselu APC se loo darapo mo egbe oselu PDP.
Awon Seneto naa ni:
Sen. Tejouso; Sen. Shaaba; Sen. Gemade; Sen. Melaye; Sen. Shittu; Sen. Rafiu; Sen. Shitu Ubali; Sen. Isa Misau; Sen. Hunkuyi; Sen. Monsurat; Sen. Danbaba; Sen. Nafada; Sen. Nazif; Sen. Kwankwaso ati Seneto Abdul-azeez Murtala-Nyako
No comments:
Post a Comment