Agbejoro naa ti won pe oruko e ni Obinna Onuoha la gbo pe ile ejo giga kinni in to wa nijoba ibile Obingwa, ipinle Abia la gbo pe asiko ti won n foro wa eni kan ti won fesun kan lenu wo lo deede subu lule.
Ohun ta a gbo ni pe, ka ni okunrin agbejoro naa tete ri itoju kereje nigba to subu lule ni, o see se ko ma gbabe soda sorun alakeji nitori pe aisan okan (cardiac arrest) la gbo pe o muu lojiji.
No comments:
Post a Comment