IDIBO EKITI: EYI NI ORO TI OBASANJO FI KI FAYEMI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, July 15, 2018

IDIBO EKITI: EYI NI ORO TI OBASANJO FI KI FAYEMI

Aare orileede yi tele, Oloye Dokita Olusegun Obasanjo ti ki Dokita Kayode Kayemi ku oriire fun bo ti se jawe olubori nibi eto idibo to waye lojo Satide to koja yi nipinle Ekiti.


Oloye Obasanjo to wa niluu China lorileede Beijing lowolowo bayii lo fi leta ikinni naa ranse si Fayemi laaro onii, nibe naa lo ti sapejuwe e gege bi adari rere tawon araalu n fe.

Leta naa lo wa nisale yii



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI