Kolawole
Abiola to je omo to dagba ju ninu awon omo oloogbe Oloye Moshood Kashimawo
Olawale Abiola ti gba awoodu tawon aare orileede Naijiria ma n gba, iyen GCON (Grand
Commander of the Federal Republic) fun baba e.
Nigba
to n gba awoodu naa, Kolawole Abiola so pe inu oun dun fun Aare Muhammadu
Buhari se ranti baba oun lasiko yi, eyi tawon Aare to ti koja lo ko se fun baba
oun.
O
loun mo pe Aare tooto ni Buhari, ti ko si nii soju saaju enikeni. Bee lo dupe
lowo gbogbo awon to sagbateru eto awoodu naa ati bi won tun se yi ojo ayeye
isejoba awarawa kuro ni ojo kokandinlogbon, osu karun si ojo kejila osu kefa
odoodun.
No comments:
Post a Comment