Fawon to ba n ba eto ife eye agbaye naa lo, Nigeria, Argentina, Croatia ati Iceland ni won jo maa figagbaga ninu ipele akoko (first round) nibi idije ti yoo bere lojo kerinla osu kefa si ojo keedogun osu keje.
Amuneke, to tun je akonimongba rgbe agbaboolu Naijiria ti ojo ori won ko ju odun metadinlogun lo (U-17), iyen awon ti won gba idije ife eye agbaye todun 2015 nigba to n soro so pe Olorun fun orileede Naijiria lebun awon agbaboolu to kun oju osuwon.
Ninu oro e, o so pe "Egbe naa ti gbe oruko orileede yi ga pelu bi won se n mura sile fun idije naa. Won gbodo ni afojusun. Awon akonimongba won gbodo wo ibi ti won ku si lati le fi bawon soro, ko si gba won niyanju.
"Awon omo Naijiria n fe e ri aseyori won. Mo gbadura fun won pe won a se aseyori."
No comments:
Post a Comment