LOBATAN: IGBAKEJI GOMINA IPINLE BAUCHI KOWE FIPO SILE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, May 24, 2018

LOBATAN: IGBAKEJI GOMINA IPINLE BAUCHI KOWE FIPO SILE

Titi di bi e ti n ka iroyin yi lopo awon eeyan ko tii le so idi pataki ti igbakeji gomina ipinle Bauchi, Nuhu Gidado fi kowe fipo e sile lojo Wesde to koja yi.


Gege b'AWIKONKO se gbo oro naa, won ni o see se ko je pe ipo naa ti suu latari ona ti gomina ipinle naa, Mohammed Abubakar n gba se ijoba e labe egbe oselu APC.

Sugbon ninu leta ti Nuhu fi ranse sileese ijoba, o je ko di mi mo pe oun wun oun lati ba gomina Abubakar pari saa ijoba e, sugbon ti ipo naa ti su oun, toun ko si le tesiwaju mo.

Ekunrere e n bo lai pe...

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI